Èdè Wa Ni: Ẹ Pàdé Olorì Sports Tó Ń Fi Ẹ̀fẹ̀ Ṣ’àtúpalẹ̀ Eré Ìdárayá Lédè Yorùbá

Èdè Wa Ni: Ẹ Pàdé Olorì Sports Tó Ń Fi Ẹ̀fẹ̀ Ṣ’àtúpalẹ̀ Eré Ìdárayá Lédè Yorùbá

Punchng | 08-07-2024 12:55pm |

A ṣe àbẹ̀wò sí arábìnrin Adérónkẹ́ Adéṣọlá Olorì Sports ní ilé iṣẹ́ Splash FM ìlú Ìbàdàn láti sọ nípa iṣẹ́ pàtàkì tí ó ń ṣe nípa ṣíṣe àtúpalẹ̀ eré ìdárayá pẹ̀lú ẹ̀fẹ̀ lórí rédíò lédè Yorùbá. Olorì Sports ṣàlàyé bí ó ṣe di ògbóǹtarìgì sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lédè Yorùbá, àwọn tí wọ́n ràn án lọ́wọ́ láti gòkè Read More

Stay Updated with the Latest News!

Don't miss out on breaking stories and in-depth articles.